Jòhánù 21:2 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Símónì Pétérù, àti Tọ́másì tí a ń pè ní Dídímù, àti Nátanáẹ́lì ará Kánà ti Gálílì, àti àwọn ọmọ Sébédè, àti àwọn ọmọ-ẹ̀yìn rẹ̀ méjì mìíràn jùmọ̀ wà pọ̀.

Jòhánù 21

Jòhánù 21:1-5