Jòhánù 21:14 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Èyí ni Ìgbà kẹ́ta nísinsin yìí tí Jésù farahan àwọn ọmọ-ẹ̀yìn rẹ̀ lẹ́yìn ìgbà tí ó jíǹde kúrò nínú òkú.

Jòhánù 21

Jòhánù 21:7-19