Jòhánù 20:29 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Jésù wí fún un pé, “Nítorí tí ìwọ rí mi ni ìwọ ṣe gbàgbọ́: alábùkún fún ni àwọn tí kò rí mi, tí wọ́n sì gbàgbọ́!”

Jòhánù 20

Jòhánù 20:19-31