Jòhánù 2:9 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Olórí àsè náà tọ́ omi tí a sọ di wáìnì wò. Òun kò sì mọ ibi tí ó ti wá, ṣùgbọ́n àwọn ìránṣẹ́ tí ó bu omi náà wá mọ̀. Olórí àsè sì pe ọkọ ìyàwó sí apákan,

Jòhánù 2

Jòhánù 2:1-18