Jòhánù 2:19 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Jésù dáhùn ó sì wí fún wọn pé, “Ẹ wó tẹ́ḿpílì yìí palẹ̀, Èmi ó sì tun un kọ ní ọjọ́ mẹ́ta.”

Jòhánù 2

Jòhánù 2:9-25