Jòhánù 2:14 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ó sì rí àwọn tí n ta màlúù, àti àgùntàn, àti àdàbà, àti àwọn onípàsípàrọ̀ owó ní tẹ́ḿpìlì wọ́n jòko:

Jòhánù 2

Jòhánù 2:11-20