Jòhánù 2:11 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Èyí jẹ́ àkọ́se iṣẹ́ àmì rẹ̀, tí Jésù ṣe ní Kánà ti Gálílì. Ó sì fi ògo rẹ̀ hàn; àwọn ọmọ-ẹ̀yìn rẹ̀ sì gbà á gbọ́.

Jòhánù 2

Jòhánù 2:9-19