Jòhánù 19:9 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ó sì tún wọ inú gbọ̀ngàn ìdájọ́ lọ, ó sì wí fún Jésù pé, “Níbo ni ìwọ ti wá?” Ṣùgbọ́n Jésù kò dá a lóhùn.

Jòhánù 19

Jòhánù 19:1-10