Jòhánù 19:5 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nítorí náà Jésù jáde wá, ti òun ti adé ẹ̀gún àti aṣọ elésèé àlùkò. Pílátù sì wí fún wọn pé, Ẹ wò ọkùnrin náà!

Jòhánù 19

Jòhánù 19:1-8