Jòhánù 19:39 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Níkodémù pẹ̀lú sì wá, ẹni tí ó tọ Jésù wá lóru lákọ́kọ́, ó sì mú àdàpọ̀ òjíá àti álóè wá, ó tó ìwọ̀n ọgọ́rún lítà.

Jòhánù 19

Jòhánù 19:29-42