Jòhánù 19:36 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nǹkan wọ̀nyí ṣe, kí ìwé mímọ́ ba à lè ṣẹ, tí ó wí pé, “A kì yóò fọ́ egungun rẹ̀.”

Jòhánù 19

Jòhánù 19:31-41