Jòhánù 19:25 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ìyá Jésù àti arábìnrin ìyá rẹ̀ Màríà aya Kílópà, àti Màríà Magidalénì sì dúró níbi àgbélébùú,

Jòhánù 19

Jòhánù 19:22-31