Jòhánù 19:18 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Níbití wọ́n gbé kàn án mọ́ àgbélébùú, àti àwọn méjì mìíràn pẹ̀lú rẹ̀, níhà ìhín àti níhà kejì, Jésù sì wà láàárin.

Jòhánù 19

Jòhánù 19:12-19