Jòhánù 19:13 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nítorí náà nígbà tí Pílátù gbọ́ ọ̀rọ̀ wọ̀nyí, ó mú Jésù jáde wá, ó sì jókòó lórí ìtẹ́ ìdájọ́ ní ibi tí a ń pè ní Òkúta-títẹ́, ṣùgbọ́n ní èdè Hébérù, Gábátà.

Jòhánù 19

Jòhánù 19:8-20