Jòhánù 19:11 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Jésù dá a lóhùn pé, “Ìwọ kì bá tí ní agbára kan lórí mi, bí kò se pé a fi í fún ọ láti òkè wá: nítorí náà ẹni tí ó fi mí lé ọ lọ́wọ́ ni ó ní ẹ̀ṣẹ̀ pọ̀ jù.”

Jòhánù 19

Jòhánù 19:3-16