Jòhánù 18:35 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Pílátù dáhùn wí pé, “Èmi ha jẹ́ Júù bí? Àwọn ọmọ orílẹ̀ èdè rẹ, àti àwọn olórí àlùfáà ni ó fà ọ́ lé èmi lọ́wọ́: kín ní ìwọ ṣe?”

Jòhánù 18

Jòhánù 18:34-40