Jòhánù 18:32 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Kí ọ̀rọ̀ Jésù ba à lè ṣẹ, èyí tí ó sọ tí ó ń ṣàpẹẹrẹ irú ikú tí òun yóò kú.

Jòhánù 18

Jòhánù 18:25-40