Jòhánù 18:2 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Júdásì, ẹni tí ó dà á, sì mọ ibẹ̀ pẹ̀lú: nítorí nígbà púpọ̀ ni Jésù máa ń lọ síbẹ̀ pẹ̀lú àwọn ọmọ-ẹ̀yìn rẹ̀.

Jòhánù 18

Jòhánù 18:1-3