Jòhánù 18:15 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Símónì Pétérù sì ń tọ Jésù lẹ́yìn, àti ọmọ-ẹ̀yìn mìíràn kan: ọmọ-ẹ̀yìn náà jẹ́ ẹni mímọ̀ fún olórí àlùfáà, ó sì bá Jésù wọ ààfin olórí àlùfáà lọ.

Jòhánù 18

Jòhánù 18:12-21