Jòhánù 17:6 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Èmi ti fi orúkọ rẹ hàn fún àwọn ènìyàn tí ìwọ ti fún mi láti inú ayé wá: tìrẹ ni wọ́n ti jẹ́ rí, ìwọ sì ti fi wọ́n fún mi; wọ́n sì ti pa ọ̀rọ̀ rẹ mọ́.

Jòhánù 17

Jòhánù 17:1-8