Jòhánù 17:3 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ìyè àìnípẹ̀kun náà sì ni èyí, kí wọn kí ó lè mọ ìwọ nìkan Ọlọ́run òtítọ́, àti Jésù Kírísítì, ẹni tí ìwọ rán.

Jòhánù 17

Jòhánù 17:2-12