Jòhánù 17:14 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Èmi ti fi ọ̀rọ̀ rẹ fún wọn; ayé sì ti kórìíra wọn, nítorí tí wọn kì í ṣe ti ayé, gẹ́gẹ́ bí èmi kì í ti í ṣe ti ayé.

Jòhánù 17

Jòhánù 17:10-24