Jòhánù 17:10 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Tìrẹ sáà ni gbogbo ohun tí í ṣe tèmi, àti tèmi sì ni gbogbo ohun tí í ṣe tìrẹ, a sì ti ṣe mí lógo nínú wọn.

Jòhánù 17

Jòhánù 17:1-16