Jòhánù 15:8 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nínú èyí ní a yìn Baba mi lógo pé, kí ẹ̀yin kí ó máa so èṣo púpọ̀; ẹ̀yin ó sì jẹ́ ọmọ-ẹ̀yìn mi.

Jòhánù 15

Jòhánù 15:6-13