Jòhánù 15:18 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Bí ayé bá kóríra yín, ẹ mọ̀ pé, ó ti kóríra mi ṣáájú yín.

Jòhánù 15

Jòhánù 15:10-20