Jòhánù 14:29 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Èmi sì ti sọ fún yín nísinsìn yìí kí ó tó ṣẹ, pé nígbà tí ó bá ṣẹ, kí ẹ lè gbàgbọ́.

Jòhánù 14

Jòhánù 14:24-31