Jòhánù 14:22 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Júdásì (Kì í se Isíkaríótù) wí fún un pé, “Olúwa, èé ha ti ṣe tí ìwọ ó fi ara rẹ hàn fún àwa, tí kì yóò sì ṣe fún aráye?”

Jòhánù 14

Jòhánù 14:12-31