Jòhánù 14:18 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Èmi kò ní fi yín sílẹ̀ láìní Òlùtùnú, kí ẹ wá dàbí ọmọ tí kò ní òbí. Rárá o! Mo tún ń tọ̀ yín bọ̀.

Jòhánù 14

Jòhánù 14:17-23