Jòhánù 13:7 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Jésù dá a lóhùn, ó sì wí fún un pé, “Ohun tí èmi ń ṣe ni ìwọ kò mọ̀ nísinsin yìí; ṣùgbọ́n yóò yé ọ ní ìkẹyìn.”

Jòhánù 13

Jòhánù 13:1-10