Jòhánù 13:34 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Òfin titun kan ni mo fi fún yín, kí ẹ̀yin kí ó fẹ́ ọmọnìkejì yín; gẹ́gẹ́ bí èmi ti fẹ́ràn yín, kí ẹ̀yin kí ó sì lè fẹ́ràn ọmọnìkejì yín.

Jòhánù 13

Jòhánù 13:25-38