Jòhánù 13:16 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Lóòótọ́, lóòótọ́ ni mo wí fún yín, ọmọ-ọ̀dọ̀ kò tóbi ju ọ̀gá rẹ̀ lọ, bẹ́ẹ̀ ni ẹni tí a rán kò tóbi ju ẹni tí ó rán an lọ.

Jòhánù 13

Jòhánù 13:13-17