Jòhánù 12:50 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Èmi sì mọ̀ pé ìyè àìnípẹ̀kun ni òfin rẹ̀: nítorí náà, àwọn ohun tí mo bá wí, gẹ́gẹ́ bí Baba ti sọ fún mi, bẹ́ẹ̀ ni mo wí!”

Jòhánù 12

Jòhánù 12:44-50