Jòhánù 12:46 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Èmi ni ìmọ́lẹ̀ tí ó wá sí ayé, kí ẹnikẹ́ni tí ó bá gbà mí gbọ́ má ṣe wà nínú òkùnkùn.

Jòhánù 12

Jòhánù 12:41-50