Jòhánù 12:44 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Jésù sì kígbe ó sì wí pé, “Ẹni tí ó bá gbà mí gbọ́, èmi kọ́ ni ó gbàgbọ́ ṣùgbọ́n ẹni tí ó rán mi.

Jòhánù 12

Jòhánù 12:41-50