Jòhánù 12:38 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Kí ọ̀rọ̀ wòlíì Ìsàíàh lè ṣẹ, èyí tí ó sọ pé:“Olúwa, tani ó gba ìwàásù wa gbọ́Àti ta ni a sì fi apá Olúwa hàn fún?”

Jòhánù 12

Jòhánù 12:35-44