Jòhánù 12:27 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Ní ìsinsin yìí ni a ń pọ́n ọkàn mi lójú; kínni èmi ó sì wí? ‘Baba, gbà mí kúrò nínú wákàtí yìí’? Rárá, ṣùgbọ́n nítorí èyì ni mo ṣe wá sí wákàtí yìí.

Jòhánù 12

Jòhánù 12:26-34