Jòhánù 12:18 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nítorí èyí ni ìjọ ènìyàn sì ṣe lọ pàdé rẹ̀, nítorí tí wọ́n gbọ́ pé ó ti ṣe iṣẹ́ àmì yìí.

Jòhánù 12

Jòhánù 12:8-23