Jòhánù 12:11 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nítòrí pé nípasẹ̀ rẹ̀ ni ọ̀pọ̀ nínú àwọn Júù jáde lọ, wọ́n sì gbà Jésù gbọ́.

Jòhánù 12

Jòhánù 12:3-20