Jòhánù 11:48 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Bí àwa bá fi í sílẹ̀ bẹ́ẹ̀, gbogbo ènìyàn ni yóò gbà á gbọ́: àwọn ará Rómù yóò sì wá gba ilẹ̀ àti orílẹ̀-èdè wa pẹ̀lú.”

Jòhánù 11

Jòhánù 11:46-51