Jòhánù 11:37 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Àwọn kan nínú wọn sì wí pé, “Ọkùnrin yìí, ẹni tí ó la ojú afọ́jú, kò lè ṣeé kí ọkùnrin yìí má kú bí?”

Jòhánù 11

Jòhánù 11:31-45