Jòhánù 11:2 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

(Màríà náà ni ẹni tí ó fi òróró ìkunra kun Olúwa, tí ó sì fi irun orí rẹ̀ nù ún, arákùnrin rẹ̀ ni Lásárù í ṣe, ara ẹni tí kò dá.)

Jòhánù 11

Jòhánù 11:1-12