Jòhánù 10:3 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Òun ni osọ́nà yóò ṣílẹ̀kùn fún; àwọn àgùntàn gbọ́ ohùn rẹ̀: ó sì pe àwọn àgùntàn tirẹ̀ lórúkọ, ó sì se amọ̀nà wọn jáde.

Jòhánù 10

Jòhánù 10:1-7