Jòhánù 10:18 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ẹnìkan kò gbà á lọ́wọ́ mi, ṣùgbọ́n mo fi í lélẹ̀, mo sì lágbára láti tún gbà á. Àṣẹ yìí ni mo ti gbà wá láti ọ̀dọ̀ Baba mi.”

Jòhánù 10

Jòhánù 10:13-26