Jòhánù 1:33 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Èmí kì bá tí mọ̀ ọ́n, bí kò ṣe pé ẹni tí ó rán mi láti fi omi bamitíìsì sọ fún mi pé, ‘Ọkùnrin tí ìwọ rí tí Ẹ̀mí sọ̀kalẹ̀ tí ó bà lé lórí ni ẹni tí yóò fi Ẹ̀mí Mímọ́ bamitíìsì.’

Jòhánù 1

Jòhánù 1:30-35