Jòhánù 1:3 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nípaṣẹ̀ rẹ̀ ni a dá ohun gbogbo; lẹ́yìn rẹ̀ a kò sì dá ohun kan nínú ohun tí a ti dá.

Jòhánù 1

Jòhánù 1:1-13