Jòhánù 1:28 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Àwọn nǹkan wọ̀nyí ni ó ṣẹlẹ̀ ní Bétanì ní òdì kejì odò Jọ́dánì, níbi tí Jòhánù ti ń ṣe ìtẹ̀bọmi.

Jòhánù 1

Jòhánù 1:24-29