Jòhánù 1:25 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

bi í léèrè pé, “Èéṣe tí ìwọ fí ń bamitíìsì nígbà náà, bí ìwọ kì í bá ṣe Kírísítì, tàbí Èlíjà, tàbí wòlíì náà?”

Jòhánù 1

Jòhánù 1:22-30