Jòhánù 1:23 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Jòhánù sì fi ọ̀rọ̀ wòlíì Àìṣáyà fún wọn ní èsì pé, “Èmi ni ohùn ẹni tí ń kígbe ní ijù, ‘Ẹ ṣe ọ̀nà Olúwa ní títọ́.’ ”

Jòhánù 1

Jòhánù 1:14-24