Jòhánù 1:20 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Òun kò sì kùnà láti jẹ́wọ́, ṣùgbọ́n òun jẹ́wọ́ wọ́ọ́rọ́wọ́ pé, “Èmi kì í ṣe Kírísítì náà.”

Jòhánù 1

Jòhánù 1:11-30