Jòhánù 1:18 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Kò sí ẹni tí ó rí Ọlọ́run rí, ṣùgbọ́n Òun, àní Àyànfẹ́ rẹ̀ kan ṣoṣo, tí ń bẹ ní oókan àyà Baba, Òun náà ni ó fi í hàn.

Jòhánù 1

Jòhánù 1:14-25